Òkè Àró Pig Village: Owó gbọdọ̀ wà lápò láti ṣètọ́jú ẹlẹ́dẹ̀

Òkè Àró Pig Village: Owó gbọdọ̀ wà lápò láti ṣètọ́jú ẹlẹ́dẹ̀

Ìlànà àrà ọ̀tọ̀, wíwá ààyè àti owó ni wọ́n fi ń mójú tó ẹlẹ́dẹ̀.

Àwọn obìnrin yìí ní ẹlẹ́dẹ̀ sinsin gba ààyè púpọ̀ fún àmójútó tó péye. gba àkókò.

Wọn wá ń rọ ìjọba láti se kóríyá fún wọn, láti lọ se kó àwọn ẹlẹ́dẹ̀ wọn lọ sí ilẹ̀ òkèèrè.

Awọn iroyin miran ti ẹ le nifẹ si: