Super eagles fi ijó bẹ́ẹ lẹ́yìn tí wọ́n ta òmì pẹ̀lú Uganda
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

AFCON 2019: Nàìjírìa àti Uganda fi ijó bẹ́ẹ ni ìlú Asaba

Inu ẹni kii dun ka pa mọnra. Bẹẹ gẹgẹ lọrọ ri pẹlu ikọ Super Eagles ati Uganda lẹyin ti wọn gba omi 0-0 ninu ifẹsẹwọnsẹ ọlọọrẹsọọrẹ lọjọ Iṣẹgun nilu Asaba.

Fidio ti ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles fi lede lori opo Twitter wọn fihan bi ẹlẹsẹ ayo Ahmed Musa, adilemun Ikechukwu Ezenwa ati awọn agbabọọlu miran ti kijo mọlẹ.

Koda akọnimọọgba ẹgbẹ agbabọọlu Naijiria Gernot Rohr ati awọn igbakeji aarẹ ajọ to n ri si ere bọọlu ni Naijiria Shehu Dikko naa ko gbẹyin ninu ijo ọhun.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: