Premier League: Àkọ́dá oró...Man City fìbínú gbèsan lára Tottenham

Son

Oríṣun àwòrán, Getty Images

B'adiẹ dami mloogun nu, maa fọ lẹyin ni Manchester City fi ṣe fun ẹgbẹ agbabọọlu Tottenham nigba ti gbẹsan bi wọn ṣe na wọn kuro ninu idije UEFA Champions League.

Ọdọmọde agbabọọlu Phil Foden lo gba goolu sawọn fun Manchester City lẹyin iṣẹju marun un ti ere bọọlu naa bẹrẹ ti City si bori pẹlu ami ayo kan sodo.

Ifẹsẹwọnsẹ ọhun gbona girigiri nitori Man City ni lati jawe olubori ki wọn le lanfaani lati gba ife ẹyẹ Premier League

Àkọlé fídíò,

Helen Paul sọ idi tó fi gba orúkọ ní kékere

Àkọlé fídíò,

Hakeem: Mo lè sọ arúgbó dí ọmọge nígbà tó bá wù mí

Manchester City lo wa loke Liverpool bayii ninu idije Premier League.

L'Ọjọrun ọsẹ to n bọ ni Man City yoo tun koju alatako wọn miran to lami laaka, Manchester United.