Kàn sí BBC Yorùbá

Lati fi ero rẹ ransẹ, jọwọ fi imeeli sọwọ si wa lori bbcyoruba@bbc.co.uk

Bi a o se gbiyanju lati ka gbogbo imeeli ti a ba gba, ko si idaniloju pe a o fesi. A le fesi is imeeli tabi ki a kan sii yin fun ekunrẹrẹ alaye.

Ti o ba fẹ fi ẹdun okan rẹ ransẹ, jọwọ lo oju iwẹ ẹdun okan wa.

Iléesẹ́ BBC ni yóò lo àwọn àkọsílẹ̀ rẹ tóo bá fi sọwọ́, àti àwọn iléesẹ́ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ táa bá gbára lé fún àtìlẹyìn wọn lórí ọ̀pọ̀ àríwísí, àti ìlànà táwọn èèyàn tó ń ka ojú òpó ìròyìn wa leè lò, fún àkójọpọ̀ ìròyìn àti gbígba èrò yín sílẹ̀. Iléesẹ́ BBC àti àwọn iléesẹ́ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ tó ń sisẹ̀ pọ̀ pẹ̀lú wa, yóò fi àwọn àkọsílẹ̀ yín pamọ́ níbàámu pẹ̀lú òfin àti ìlànà fífi àkọsílẹ̀ pamọ́. Iléesẹ́ BBC ń lo àwọn àkọsílẹ̀ rẹ níbàámu pẹ̀lú ìwúlò wọn àti ìlànà òfin gẹ́gẹ́ bíi iléesẹ́ ìròyìn tẹ́ ń kàn sí, táa sì tún ń fèsì padà lóríi àwọn èrò àti ìbéèrè àwọn èèyàn tó ń kàn sí wa. Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìmọ̀ nípa ọ̀nà tí BBC ń gbà lo àwọn àkọsílẹ̀ yín, ẹ kàn sí ojú òpó BBC tó ń sọ nípa ìlànà báa se ń tọ̀jú ìròyìn ìdá-kọ́ńkọ́ àti àsírí - BBC's Privacy and Cookies Policy. Tí o bá se àríwísí nípa ọwọ́ tí BBC gbà mú àkọsílẹ̀ rẹ, tí àlàyé wa kò sì tẹ́ ọ lọ́rùn, o tún leè fi ọ̀rọ̀ yìí tó ọ́ọ́fìsì Kọ́misánà fétò ìròyìn létí.

Àlàyé kíkàn sí ọ
Sísẹ́ ọ̀ràn