Ẹ fi ẹ̀dùn ọkàn yín ránsẹ́ si BBC Yoruba

Lati fi ẹdun ọkan yin ransẹ, jọwọ fi imeeli sọwọ si wa lori bbcyoruba.complaints@bbc.co.uk.

A o gbiyanju lati fesi laarin ọjọ merinla sugbọn o da laer irufẹ ohun ti ibeererẹ da lori ati irufẹ awọn bee ti a ni lati se iwadi le lori ati ti a ni lati fesi si.

Jọwọ ka "Ohun ti yoo sẹlẹ si ibeere mi" (ni ede Geesi) fun ekunrẹrẹ alaye lori bi a se n yanju koko inu ibeere ati esi ti a ba gba.

Fun gbogbo ibeere, jọwọ lo oju iwe ifesi pada wa.

Iléesẹ́ BBC ni yóò lo àwọn àkọsílẹ̀ rẹ tóo bá fi sọwọ́, àti àwọn iléesẹ́ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ táa bá gbára lé fún àtìlẹyìn wọn lórí ọ̀pọ̀ àríwísí, àti ìlànà táwọn èèyàn tó ń ka ojú òpó ìròyìn wa leè lò, fún àkójọpọ̀ ìròyìn àti gbígba èrò yín sílẹ̀. Iléesẹ́ BBC àti àwọn iléesẹ́ ìbáraẹnisọ̀rọ̀ tó ń sisẹ̀ pọ̀ pẹ̀lú wa, yóò fi àwọn àkọsílẹ̀ yín pamọ́ níbàámu pẹ̀lú òfin àti ìlànà fífi àkọsílẹ̀ pamọ́. Iléesẹ́ BBC ń lo àwọn àkọsílẹ̀ rẹ níbàámu pẹ̀lú ìwúlò wọn àti ìlànà òfin gẹ́gẹ́ bíi iléesẹ́ ìròyìn tẹ́ ń kàn sí, táa sì tún ń fèsì padà lóríi àwọn èrò àti ìbéèrè àwọn èèyàn tó ń kàn sí wa. Fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìmọ̀ nípa ọ̀nà tí BBC ń gbà lo àwọn àkọsílẹ̀ yín, ẹ kàn sí ojú òpó BBC tó ń sọ nípa ìlànà báa se ń tọ̀jú ìròyìn ìdá-kọ́ńkọ́ àti àsírí - BBC's Privacy and Cookies Policy . Tí o bá se àríwísí nípa ọwọ́ tí BBC gbà mú àkọsílẹ̀ rẹ, tí àlàyé wa kò sì tẹ́ ọ lọ́rùn, o tún leè fi ọ̀rọ̀ yìí tó ọ́ọ́fìsì Kọ́misánà fétò ìròyìn létí.