Got a TV Licence?

You need one to watch live TV on any channel or device, and BBC programmes on iPlayer. It’s the law.

Find out more
I don’t have a TV Licence.

Jíjábọ̀ ohun tí ń lọ lọ́wọ́

Nípasẹ̀ Abdulwasiu Hassan

Gbogbo àkókò tí a kọ jẹ́ ti UK

 1. Ẹ ka bí ìjíròrò náà ṣe lọ

  Ẹ ka bí ìjíròrò ṣe lọ láàrin àwọn tó ń du ipò gómìnà ìpínlẹ̀ Eko níbi ìpàdé ìtagbngba BBC News Yorùbá.

 2. Gbadamosi lórí ilé olówó pọ́kú

  Gbadamosi ní òhun yóò kọ́ ilé olówó pọ́kú 40,000 lẹ́yìn náà yóò sì fún àwọn iléeṣẹ́ tó ń kọ́lé tà ní ààyè àti kólé fún àwọn èèyàn.

 3. Ètò àwọn olùdíje lórí àwọn àkàndá ènìyàn

  Olùdíje

  Fafoworaní ijoba gbọ́dọ̀ wá idà owó kan láti máa ṣe iṣẹ́ wọn gbọ́dọ̀ empower wọn. Kí wọn kò ìṣe kí ìjọba náà sì máa fún wọn ní isẹ.

  Adesanya ní mo lọ sí àárín àwọn afọ́jú, mo sì rí pé wọn mowe gidi, ó ṣe pàtàkì láti kó ilé fún wọn, wọn ń ṣe iṣẹ́ owó tí ó bá dé òkè òkun yóò ta Àwọn ilé ìṣe gbodo máa gba wọn sì ìṣe 2% at least

  Gbadamosi ní Akanda èèyàn kii se ẹni tí ènìyàn ń korira. Gbogbo ilé ìṣe ijoba gbọ́dọ̀ ṣe ona ibi tí àwọn akànda máa gba Àwọn ilé ìwé gbodo je ibi ti wọne ni anfaani lati wo. Àwọn náà gbodowje anfaani tí àwọn tó kú ní.

  Ogunsanya ní ìjọba tèmi yóò máa mójú tó àwọn ènìyàn yìí, àwọn ilé ìwé ara oto tí jẹ tiwọn ni wọ́n ó máa kọ ẹ̀kọ́ kí wọn lé wúlò fún àwùjọ

 4. Adesanya fẹ́ dá àwọn oníṣẹ́ ọwọ́ lókowò

  Adesanya
  Image caption: Adesanya

  Adesanya ní àwọn yóò dá àwọn oníṣẹ́ ọwọ́ lókowò. , àti àwọn iṣẹ́ ọwọ́( vocational skills). Àwọn to wá ni garaji, wọn a kò wọn sì ipele ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ níbi tí wọn a ti ní. Olórí tí yóò máa lànà fún wọn. Wọn gbọ́dọ̀ tẹ́lẹ̀ ofin Industrial park, ọ̀pọ̀ ìṣe ni àwọn ènìyàn yìí yóò Máa ṣe nibẹ

 5. Ogunsanya lórí ààbò

  Ogunsanya lórí ààbò owó tó dilẹ̀ ni Èṣù ńlò, ẹni tó bá ní ìṣe tó ń ṣe kii hùwà ipanle, ètò eko wọn yóò máa dùn jí ànfàní láti lè ronú. A máa pè wọn sì àwùjọ ààlàbe sekele láti bá wọn sọ̀rọ̀.

  Ogunsanya
 6. Gbadamosi lórí ètò ààbò

  Lórí ètò Ààbò. Gbadamosi ní àìní isẹ́ jẹ́ nǹkan tó ń fàá tí àwọn ènìyàn láti máa hùwà janduku.

  Àwọn onímótò, ìṣòro ò ju nkan ti àwọn olóṣèlú dá sílè lọ. Àwọn ìlànà tí wọn á fi tún ṣe ọwọ́ olóṣèlú náà lọ wà. Wọn dá àwọn awakọ̀ lọ́wọ́ kò láti má fi ipanle gba owó mọ́.

  Gbadamosi
 7. Adesanya àti Ogunsanya sọ̀rọ̀ lórí ìlera

  Debate

  Adesanya ní gbogbo nǹkan tó yẹ lọ gbọ́dọ̀ wá níbè kìí ṣe kí á kò ìlé ìwòsàn nìkan. Àwọn nọ́ọ́si ó gbà ẹ̀kọ́ tuntun. Wọn ò gbà dókítà. Àwọn generator ṣe pàtàkì láti máa lé demi àwọn ènìyàn lè gbodo. Owó tí ó yẹ kí wọn san fún àwọn òṣìṣẹ́.

  Ogunsanya ní àwọn máa ṣe àyẹ̀wò owó tí wọn ń ṣàn fún àwọn dókítà àti Noosi. Àwọn health Centre yìí wá kò sì General hospital. Ọ̀pọ̀ lọ ti kú kí wọn tó gbé de ile iwosan. Ó pọndandan kii àwọn òṣìṣẹ́ máa wà ní 24hours

 8. Gbadamosi

  Gbadamosi ní Eto ìlera gbodọ̀ jẹ́ ọ̀fẹ́ fún àwọn ará Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó ní àwọn aboyún àti ọmọ wẹ́wẹ́ ni gbodọ̀ jẹ́ àmọ́jútó .

 9. Ọ̀rọ̀ lórí ìlera lókàn

  Ọ̀rọ̀ lórí ìlera ló kàn.

 10. Gbadamosi ní ó ṣe kókó

  Gbadamosi ní ó ṣe kókó kí gbogbo ará Eko mo bí ìjọba ṣe ń ná owó ará ìlú. Ìṣe wá ní owó tí wọn ń ná. Ẹni kookan lẹ́tọ̀ọ́ láti mọ bí wọn ṣe ń ná owó tí wọn nná. Owó tí ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ń ná lórí títì ju ti Dangote lọ.

 11. Ìbèrè lórí ẹ̀sùn ìnáwó ìjọba Eko

  Ìbérè lórí ẹ̀sùn ìnákúnáà fún ìjọba ìpínlẹ̀ Eko.

 12. Gbadamosi fi ẹ̀sún kan ìjọba ìpínlẹ̀ Eko

  Gbadamosi fi ẹ̀sún kan ìjọba ìpínlẹ̀ Eko pé wọ́n ti bu owó lu rélùwéè tí wọ́n ṣe jù. Ó ni àwọn owó tí wọn jì ni kò jẹ ki wọn san owó tó tọ́ fún ara ilu. Ó ní iṣe Danfo òún kọ́kọ́ ṣe láyé rẹ̀.

 13. Ìbérè fún Gbadamosi

  Ìbérè fún Gbadamosi ti ADP : Báwo ni wọ́n ṣe fẹ́ ṣe ìjọba tí wọn ò fi ní ṣe bámúbámú ni mo yó.

 14. Ogunansay YPP sọ pé

  Ogunansay YPP sọ pé .. ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ tó jáde nílé Eko ti ko ri isẹ. Wọn a sì ọ́fíìsì sì ijoba ibile láti lọ forúkọ silẹ losoose, tí ààyè bá ti sì silẹ wọn a fi wọn bẹ, ẹni tó bá nílò eko sii wọn ṣe. Ohun ibanuje ni pé àwọn odò tí ń wọ ẹgbẹ́ kegbe

  Ogunsanya
 15. Ìbérè láti ọwọ́ aráìlú

  Ìbérè láti ọwọ́ aráìlú lókàn. Ìbérè fún olùdíje YPP sọ pé kí ni ó yàtọ̀ tí wọn fẹ́ ṣe fún àwọn odò tí kò rí ìṣe ṣe.

 16. Adesanya lórí owó orí

  Adesanya ní kò sì nǹkan tó burú nípa sísan owó orí, owó tí wọn ń ṣàn pò ju àwọn olówó lọ. Wọn ò ṣàyẹ̀wò finifini láti ṣe ayẹwo owó orí, a ó máa ṣe àdápadà owó.

  ADESANYA
 17. Gbadamosi

  Gbadamosi sọ pẹ́ àwọn ó máa ṣe àlàyé bí wọ́n ṣe ń ná owó orí náà fún àwọn ará ìlú.

 18. Ogunsanya lórí owó orí

  Ogunsanya ní wọ́n á máa gbé ìwé owó órí síta, oṣiṣẹ ìjọba lọ ń ṣan owó orí jù, ìjọba á máa fi hàn bí wọn ṣe ń gba owo orí.

 19. Fafowora sọ̀rọ̀ lórí owó orí

  Fafowora ní wọn á máa kọ́ àwọn ènìyàn lẹ́kọ̀ọ́. Wọ́n á máa fi owó orí sise ilu.

 20. Gbadamosi lórí ìdọ̀tí kíkọ́

  Gbadamosi ní ojúṣe ijoba ibile ni ìdọ̀tí kíkó ṣùgbọ́n wọn ò ní dáa dá wọn, wọn lọ fún "Eko recycling."

  Gbadamosi ní wọn ò ṣe òfin pé PSP gbọ́dọ̀ fowosowop pẹ̀lú ìjọba ìbílẹ̀ láti máa kọ́ ìdọ̀tí.