Ẹgbẹ́ òṣèlú ANC fẹ́ ki Jacob Zuma o kọ̀wé fi ipò sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ààrẹ South Africa.

Àwọn ẹ̀sùn tí o nìíṣe pẹlu ìwà ìjẹkúùjẹ ni wọn fi kan.