Aarẹ ilẹ Amẹrika ni oun yoo koju agbebọn to pa ọmọ ile-iwe mẹtadinlogun ni Florida.
Aarẹ ilẹ Amẹrika ni oun yoo koju agbebọn to pa ọmọ ile-iwe mẹtadinlogun ni Florida.
Lẹyin isẹlẹ ti agbebon pa eniyan mẹtadinlogun ni ile-iwe Florida, ariyanjiyan tẹle bii ọlọọpa kan se sa lasiko isẹlẹ naa.