Aworan abẹwo Aarẹ Buhari si ipinlẹ Plateau
Aarẹ Muhammadu Buhari n ṣe abẹwo ọlọjọ meji si ipinlẹ Plateau.

Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad
Ogunlọgọ awọn eniyan tu jade si oju popo lati kii Aarẹ Buhari kaabọ si ipinlẹ Plateau lọjọ ọjọbọ.
Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad
Awọn alakoso aabo fun aarẹ Buhari ni idokukọ awọn eeyan ti wọn rọ jade soju ọna.
Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad
Ọdọmọkunrin kan duro si oju ọna niwaju ọkọ ayọkẹlẹ Aarẹ Buhari
Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad
Ọdọmọkunrin kan duro si oju ọna niwaju ọkọ ayọkẹlẹ Aarẹ Buhari nipinlẹ Plateau
Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad
Aarẹ Buhari ṣe ipade pẹlu awọn alẹnulọrọ nipinlẹ Plateau
Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad
Ipade Aare Buhari pelu awon loba-loba nilu Jos
Oríṣun àwòrán, @BashirAhmaad
Awọn eniyan ipinlẹ Plateau tu jade si oju popo fun igbalejo Aarẹ Buhari