Nigeria fẹ kọ ileeṣẹ fọpo-fọpo kekere meji

ileeṣẹ fọpofọpo Image copyright Getty Images

Ijọba Naijiria fe ṣe agbẹkalẹ ẹrọ fọpo-fọpo kekere meji ni ẹkun Niger Delta ti wọn ti n wa ẹpo rọbi.

Ileese iroyin Naijiria (NAN) ni atejade kan lati ọdọ igbakeji aarẹ, Yemi Ọsinbajo, sọ wipe ipinlẹ Delta ni yoo gbalejo ọkan lara awọn ẹrọ naa to ti de Naijiria, ati wipe ẹlẹkeji to n bọ ninu osu kẹrin yoo kalẹ sipinlẹ Rivers.