Ọmọbinrin Dapchi: Mi o lọ sile iwe mọ
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọmọbinrin Dapchi: Mi o lọ s'ile iwe mọ

Ọmọbinrin Dapchi nigba to n ba BBC Sọrọ salaye ohun ti oju wọn ri ni ihamọ ikọ Boko Haram, ati bii marun ninu wọn se doloogbe nigba ti wọn n ji wọn gbe nile ẹkọ wọn.

Awọn iroyin miran ti ẹ le nifẹ si: