Ẹlẹ́wọ̀n gba máákì 248 ni ìdánwò Jamb
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ẹlẹ́wọ̀n: Ẹ̀sùn ìbálòpọ̀ ọmọdé ló gbé dé mi dé ẹ̀wọ̀n

Ẹlẹ́wọ̀n kan gba máákì 248 nínú ìdánwò Jamb ní ọgbà ẹ̀wọ̀n Ìkòyí ní ìlú Èkó.

BBC Yorùbá fẹsẹ̀ kan débẹ̀, tó sì sọ fún wa pé isẹ́ Onímọ̀ ẹ̀rọ ni òun fẹ́ se.

Olùdarí ọgbà ẹ̀wọ̀n Ìkòyí, Ìbíkúnlé Àbáyọ̀mí Idris ni, ẹlẹ́wọ̀n méjìlá ló yege ìdánwò UTME náà.

Ó ní àwọn ti ń gbìyànjú láti bẹ iléẹjọ́ pé kó fún ẹlẹ́wọ̀n yìí lááyè láti lọ sílé ẹ̀kọ́ gíga.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: