Fídíò yìí ní kẹ́ má fi òkú Aisha pa owó
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ọmọge Campus: Lọla Alao ní ẹbí Aisha kò tọrọ owó

Gbajúgbajà òṣèré tíátà Yoruba obìnrín nì, Lola Alao, tó tún jẹ́ ọ̀rẹ́ timọ-timọ pẹlu olóògbé Aishat Abimbola tó jáde láyé, lẹ́yin tí ó ní ààrùn jẹjẹrẹ ọyàn, ti sọ̀rọ̀ lórí ikú ọrẹ́ rẹ̀.

Bakan naa ni Lọla Alao tún ṣe ìkìlọ̀ fawọn Arijẹ ni idi madaru lati mase fi ikú Aishat pa owó.

O tun ni awọn kò tọrọ owó làti sin oku Aishat rara o.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: