Fayemi yan igbakejì rẹ̀ fún ìdíje gómìnà ìpínlẹ̀ Ekìtì

Kayọde Fayẹmi Image copyright Kayode Fayemi
Àkọlé àwòrán Fayemi yan Egbeyemi, ẹni ọdún mẹrìnléláàdọ́rin lẹ́yìn ìpàdé àwọn àgbàgbà ẹgbẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákátí

Olùdíje gómìnà lábẹ̀ òṣèlú APC nínú ìdìbò tó ń bọ nípìnlẹ̀ Èkìtì, John Fayemi, ti yan alága ìjọba ìbílẹ̀ Ado-Ekiti, Olóyè Adebisi Adegboyega Egbeyemi Attahiru Jega pe àwọn Asòfin ní olè gẹ́gẹ́ bíi igbákejì rẹ̀.

Nínú àtẹ̀jáde kan láti ilé ìṣẹ́ ìpolongo JKF nílù Ado-Ekìtì fi hàn pé Fayemi yan Egbeyemi ẹni ọdún mẹrìnléláàdọ́rin lẹ́yìn ìpàdé àwọn àgbàgbà ẹgbẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákátí.

Wole Olujobi tó buwọ lùwé ọ̀hún ní ẹgbẹ yan CAN ní kí wọn fágile ìdánwò ọlọ́pàá Egbeyemi lẹ́yìn awuyewuye tó gbòde pé gbajúgbajà ọmọ ìlú míìrán ní Fayemi yàn láti jọ kọ́wọ́rín nínú ìdíje gómìnà ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹfà ọdún yìí.

Ọmọ bíbí ìlú Ado-Ekìtì ní Egbeyemi, a bíi ní ọjọ́ kẹjọ, oṣù karùn-ún, ọdún 1944.