'Ìyá Alágbo' di ìbéèrè ńlá lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn

'Ìyá Alágbo' di ìbéèrè ńlá lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn

Ìpèkupè ni èèyàn máa ń pe ọ̀rọ̀ Yorùbá tí kò bá ní àmì

Ó ṣeéṣe láti máa fi òjò pe òjó, ìgbà pe igbá, ọ̀bẹ pe ọbẹ̀, owó pe òwò, ọwọ́ pe ọwọ̀ àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

'Ìyá Alágbo' (ìyá tó ń ta àgbo) ni ìbéèrè ńlá lóri abala ṣé o gbọ́ Yorùbá tòní. Àwón kan gbàá, àwọn míràn ṣìí. Ìdáhùn rẹ̀ ni: do-mi (ìyá) re-mi-re (alágbo).

BBC Yorùbá fi ń kọnílẹ́kọ̀ọ́ pẹ̀lú àwàdà ni.

Aṣà Yorùbá kò gbọdọ̀ kú; bẹ́ẹ̀ ni èdè Yorùbá kò gbọdọ̀ parun ni ìran yìí. Iṣẹ́ di ọwọ́ ìwọ àti èmi.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àṣà Yorùbá bíi ìbọ̀wọ̀fágbà,ìkíni,ìwọṣọ àti àwọn míràn jẹ́ ọ̀nà ti ìran Yorùbá fi ń kọ́ ọmọ wọn ní ẹ̀kọ́ ọmọlúwàbí ni àwùjọ.