Ọ̀jọ̀gbọn ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì rọYoruba lári mójú to àsà àti ìṣẹ̀ṣe

Ọ̀jọ̀gbọ́n Barber Karin àti àwọn égbẹ obinrin
Àkọlé àwòrán Ọ̀jọ̀gbọ́n Barber Karin ti ilé ìwé Birmingham ló rọ ẹ̀yà Yoruba bẹ́ẹ̀ láti fóju àsà yanjú ìsoro tó ń ṣẹ̀lẹ̀ láwùjọ.

Àwọn ohun to wà nínú ewì Yoruba pọ̀ nínú ohun tó ń farahan nínú igbe aye ojojumọ ilè kárọ̀-oò-jíire

Ọ̀jọ̀gbọ́n Barber Karin ti ilé ìwé Birmingham ló rọ ẹ̀yà Yoruba bẹ́ẹ̀ láti fóju àsà yanjú ìsoro tó ń ṣẹ̀lẹ̀ láwùjọ.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionPlateau: Àsìkó tó láti fi káádì ìdìbò yanjú ọ̀rọ̀ Buhari
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionÀyàn: Ti mo bá ti gbọ́ ohùn ìlù ni àárẹ́ mi ma ń lọ!

Ó ọ̀hún nínú ọ̀rọ̀ àpilẹkọ rẹ̀ níbí ayẹyẹ kan nílù Oshogbo.

Ó ní kí àwọn yorùbá máà kó ẹyin àsà Yoruba sínú agbọ̀n kan, nítori fífi onírúurú ojú wo àsà Yoruba lọ̀nà àbáyọ.

Ọ̀jọ̀gbọ́n Barber ní tí wọn ba fi ojú pàtakì àsà ilẹ̀ Afíríkà àti àwọn ìtan wọn sínu ìṣèṣe, yóò ràn wọn lọ́wọ́ láti rí ojúutu sí àwọn ńkan to ti ṣẹlẹ̀ sẹ́yìn, bákan náà ọ̀nà àbáyọ yóò wà fún àwọn nkan tó ń ṣẹlẹ̀ lásìkò yìí àtí ìsòro àgbáye lọ́jọ́ iwájú.

Related Topics