Ọdún wo ni Nelson Mandela gba ÀmÌ Ẹ̀yẹ Nobel Peace prize?

Nelson Mandela, to jẹ aarẹ alawọdudu akọkọ, ni orilẹede South Africa ni wọn sọ si ẹwọn pẹlu awọn ajijagbara miran, ti wọn si tu si lẹ ni odun 1990 lẹyin ọdun mẹtadinlọgbọn.

O ku ni Ọjọ Karun, Osu Kejila, ọdun 2013 ni ọmọọdun marundinlọgọrun. Ọmọ ọgọrun ọdun ni ko ba pe ni ẹni kani o wa laye.

Ko pa ninu idanwo yii lati mọ boya o mọ nipa Nelson Mandela.