Mò fẹ́ jẹ gómìnà láti wá ọna abayọ si isoro Yoruba - Sẹgun Ọdẹgbami
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Segun Ọdẹgbami: Mo kọ̀ láti lọ sí APC àti PDP nítorí ń kò fẹ́ ní ‘Bàbá ìsàlẹ̀’

Agbabọọlu tẹlẹri to lamilaaka, Sẹgun Ọdẹgbami to n dije dupo gomina ni ipinlẹ Ogun labẹ ẹgbẹ oselu Labour Party sọ pe ilẹ Yoruba ni gbogbo nkan to nilo lati jẹ ori ni gbogbo agbayẹ, amọ awọn oloselu ko fi ọgbọn ati ero awọn eniyan se.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: