Sé o leè kópa nínú ìdíje jíjẹ ata tútù ?
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

Ìdíje ata tútù: Sé o leè kópa nínú ìdíje jíjẹ ata tútù?

Idije ata tutu ni agbegbe Human ni orilẹ́ ede China kii se ere rara.

Laarin isẹju kan ni ẹni to bori idije naa jẹ ata aadọta, to si gba ẹbun owo goolu to jẹ giramu mẹta.

Oludije mejila lo kopa ninu idije naa.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí: