NCC Sim Registeration: Bi o ṣe lè mọ̀ tí káádì inú ẹ̀rọ ìléwọ rẹ kò bá sí nínú àkọsílẹ̀

NCC Sim Registeration: Bi o ṣe lè mọ̀ tí káádì inú ẹ̀rọ ìléwọ rẹ kò bá sí nínú àkọsílẹ̀

Ijọba apapọ Naijiria ni awọn kaadi inu ẹrọ ilewọ to ju aadọrun miliọnu lọ ni awọn to ni wọn ko ṣe iforukọ silẹ to kun oju osunwọn.

Wọn si tun ni ẹwọn ọdun marundinlọgbọn ni ijiya ẹni to ba n ta kaadi ti wọn ti fi orukọ rẹ silẹ ki ẹni to ra to de.

Ọrọ yi nkan awọn ara ilu lominu ni ikọ BBC ba lọ fi ọrọ wa awọn ti o n ṣe iforukọsilẹ kaadi wọn yi lẹnu wo.

Ẹ gbọ ohun ti wọn ni ki ara ilu ṣe nipa fifi orukọ silẹ lọna to tọ ati to yẹ.

Àwọn ìròyìn tí ẹ lè nífẹ̀ẹ́ sí: