Ẹ wo ìyà tí àwọn tí àwọn ènìyàn ń jẹ látí de Amẹ́ríkà!
Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ

African Migrants: Awọn arinrinajo sọ iriri wọn lọ si ilẹ Amerika

Ile isẹ BBC tẹle awọn ọmọ ilẹ Afirika to n wa atipo nilẹ miran.

Awọn won yiii fi ẹsẹ rin lọ ninu igbo aginju ilẹ Colombia funfun ọpọlọpọ ọjọ

O le ni eniyan 3,500 ti wọn la aginju Darién Gap ni ọdun 2019.