IRememberWhen: Àràmànda ni ǹkan ti ẹlọmiran ń ránti

Igbàkan o lọ bi òréré, àkisà náà ti lògbà rí, gbogbo èniyàn lo ti ni àsìkò kan tàbi omíràn ti wọ́n ko le gbàgbé láilái.

Àkọlé àwòrán Kíni ẹyin rànti nínú nkan ti o ti ṣẹlẹ lọ́dun díẹ̀ sẹ́yìn àti nísìnyìí

Ní ọjọ oni, ǹkan tí àwọn ọmọ Nàìjíríà ń sọ ni mímú ìránti wọ́n pàda si ìgbà àtẹyin wá. Lara ǹkan ti àwọn ọmọ Nàìjíríà ń sọ n rèé lójú òpó twitter wọ́n.

Àkọlé àwòrán #IRememberWhen: Kíni ẹyin rànti nínú àkna ti ẹ n ṣe tẹ́lẹ̀

Bí àwọn kan ṣe ń sọ nípa bi ìmẹẹrọ àti ìbanisọrọ̀ ṣe rí nbẹ́ẹ̀ ni àwọn míràn ń ránti àwọn àjálu to ti wáye sẹ́yìn

Image copyright Huw Evans picture agency
Àkọlé àwòrán #IRememberWhen: Kíni ẹyin rànti nínú àkna ti ẹ n ṣe tẹ́lẹ̀

Ṣe ẹyin naa ba wọn la eekana Gowon tyabi ẹ jẹ iru bisikii yii?

Jazz àtàwọn orin àtijọ́ tẹ́ ò mọ̀ pé ẹ ṣì lè rí gbọ́

Iléeṣẹ́ BBC fi ètò "Aim High" lọ́lẹ̀ fún àwọn àkàndá ẹ̀dá

Fasiti Eko ti "Cold Room" ni Staff Club wọn pa látàri ìwádìí BBC lórí àwọn olùkọ́ kan

Ìṣesí Kunle Ọlasọpe ni mo ṣe yan iṣẹ́ akọ̀ròyìn láàyò - Lekan Alabi

Àkọlé àwòrán Lilo èedu láti kun patako ikowe

'Ìṣòro àìrílégbé ló burú jùlọ nínú ìṣòro ẹ̀dá láyé'

Kí ló dé táwọn ọ̀dọ́ dìbò 140m fún BBNaija àmọ́ tí ìbò ààrẹ Nàíjíríà jẹ́ 28m?

Wo ìdí to fi gbọdọ̀ yàgò fún Bobrisky, akọ tó ń ṣe bíi abo

Sanusi Adebisi Idikan rèé, olówó tó ń san owó orí fún gbogbo ọkunrin ilẹ̀ Ibadan

Àkọlé àwòrán #IRememberWhen: Kíni ẹyin rànti nínú àkna ti ẹ n ṣe tẹ́lẹ̀

Ọpọ awọn ọdọ asiko yii ni wọn ko jẹgba ri tori pe wọn fọ́ ẹyin lantani oke yii; ṣugbọn awa kan jẹ ẹgba ati igbaju olooyi tori pe ẹyin lantaani oke yii jabọ lọwọ wa.

Àwọn àmúyẹ fun gbígbọ́ orin ko le ṣiṣẹ lori ẹ̀rọ rẹ
Media captionAfrica Eye: Olùkọ́ méjì ní fásitì Eko àti Ghana lùgbàdì ọ̀fíntótó BBC lórí ìwà ìbàjẹ́
Àkọlé àwòrán Owo to kere julọ ni Naijiria

Efunjoke Coker: Abiyamọ́ tó ṣé atọna àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìnrin Queens College

Gbèsè niye èèyàn tó pọ̀ ní Nàìjíríà kìí ṣe dúkìá- Emir Sanusi

Kí ló mú kí Adájọ yin ìbọn lu ará rẹ láyà nílé ẹjọ́?

Ilé aṣọ̀fin Nàìjíríà ń gbèrò ẹ̀wọ̀n f'áwọn olùkọ̀ tó bá dẹnu ìfẹ́ kọ akẹ́kọ̀bìnrin