Bobrisky:'Mo bá ẹni tó kọlu mọ́tò mi jà bí pé mo mu ǹkan ní'

Idris Okunleye Image copyright @Bobrisky
Àkọlé àwòrán Ìjà ìgboro rèé o, ṣe bí ọkun ni Bobrisky ṣe ba ọkùnrin ẹgbẹ́ rẹ̀ jà ní?

Ilúmọ̀ọ̀ká gbajumọ tó n ta àsara lóge Idris Olarewaju Okuneye ti gbogbo eniyan mọ sí Bobrisky tí fi ara rẹ̀ han bí ọkunrin.

Ní àgbegbe Jankande ni Lekki ní ọkunrin kan ti fi móto gbá móto tí Bobrisky rà ní ẹgbẹ̀lẹgbẹ̀ mílíọ̀nu naira lásìkò tó ṣe ayẹyẹ ọjọ ibí rẹ̀ nínú oṣu kẹjọ.

Nínú fárán ti ẹni kan ti ọ̀rs náà ojú rẹ̀ fi lede ni a ti rí bi ọkunrin náà ṣe àti Bobrisky ṣe wọdimu lẹ́yìn ti ọ̀kunrin náà la fóònù Bibrisky mọlẹ ti oun náà si fi ìbinu mú fóònu ọkún oun.

Ẹ̀wẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ tirẹ̀ lóju òpó Instgram rẹ ni Bobrisky ti fèsì lẹ́yìn ti ọkunrin náà bẹ̀rẹ̀ si ni bẹẹ pe èdè aiyede kékere ló bẹ́sílẹ̀ láàrin awọn, sùgbọ́n Bobriksky ni ko ri bẹ́ẹ̀ oo, kìí ssi ṣe ọ̀rs ti àwọn yóò foju fò.

"mí o ba ti jk ki o maa lọ láàlafia, sùgbọ́n ikwọ lo fi ọwọ ara rẹ fa wahala, inu mi si du pé mo wọ̀n kún fún ọ, ti o ba pàde ènìyàn ti oo mọ ri ni ọjọ míràn, o maa fi ara balẹ̀ láti mọ irú ẹni ti wọ́n jẹ́"

"Mo jà bí ẹní pé mo mú nkan ni"

Bobrisky fi kún pé bi oun yóò ba tilẹ̀ gba ẹ̀bẹ̀ rẹ̀ yóò sùn mọjú ní àgọ́ ọlọàá yóò ra fóònù túntun Iphone X Max bákan náà ni yóò tún móto oun ṣe.

Bakan náà ni àwọn ọmọ Naijiria ní kóòtu twitter ti bẹ̀rl si ní dájọ bóya ẹni náà jẹbi