Coronavirus Vaccine: Ṣé abẹrẹ àjẹsára ti wà fún àrùn COVID-19?

Coronavirus Vaccine: Ṣé abẹrẹ àjẹsára ti wà fún àrùn COVID-19?

Lẹyin ti arun Coronavirus di tọrọ fọnkale lọpọ orilẹede kaakiri agbaye, ọpọ awọn eeyan lo ti bẹrẹ si n wa abẹrẹ ajẹsara arun naa.

Awọn kan tilẹ n wa ibi ti wọn ti lee ri abẹrẹ ajẹsara ọhun naa lori itakun agbaye.

Ṣugbọn o ṣeni lanu pe, gẹgẹ bi ọrọ ti ajọ to n risi eto ilera lagbaye WHO ṣe sọ, ko tii si abẹrẹ ajẹsara arun ọhun.

Bi ọrọ ṣe jẹ wa ninu fidio yii.