Gbajugbaja osere, Yemi Elesho ti sọ iriri re ki o to di ilumọọka ni ẹka amuludun

Gbajugbaja osere, Yemi Elesho ti sọ iriri re ki o to di ilumọọka ni ẹka amuludun

Gbajugbaja osere, Yemi Elesho ti ni baba oun ko ṣe faramọ pe ki oun ṣe ere cinema ki oun to lọ si ile iwe giga.

Yemi sọ eleyii lasiko to n ba BBCYoruba sọrọ lori oun ti oju rẹ ri to di ilumọọka ni ẹka amuludun.

O ni bayii, inu baba oun dun si oun nitori oun ti n ri owo mu wale.

Ibere kii se oni'sé ni òrò náà fun idi eyi, o gba awón ọ̀dọ́ lati tepa mọ́ isẹ́ to wu wọ́n lati se.

Ẹ wo ẹkunrẹrẹ fidio naa wa:

Yemi Elesho