Pangolin Covid-19: Ẹ wo ẹranko (Akíka) tó ṣeéṣe kó ní ǹkan ṣe pẹ̀lú àrùn Coronavirus!

Pangolin Covid-19: Ẹ wo ẹranko (Akíka) tó ṣeéṣe kó ní ǹkan ṣe pẹ̀lú àrùn Coronavirus!

Ẹranko pangolin ti Yoruba n pe ni Akíka ni awọn afi ẹranko ṣowo maa n jigbe julọ ninu awọn ẹranko lagbaye.

Awọn ọlọpaa niyii nibi ti wọn mu awọn ti ọwọ palaba awọn aji ẹranko gbe ni Segi ni orilẹ-ede South-Africa.

Akika yii ni ọpọ Yoruba gbagbọ́ pe alaboyun ko gbọdọ nitori pe ọmọ rẹ yoo maa tiju pupọ to ba bii.

Awọn ara ilẹ China maa n lo ẹranko yii fun iwosan oogun ibilẹ, ti ọpọlọpọ si ro wi pe wọn ni agbara iwosan.

Amọ, iwadii ti awọn onimọ sayẹnsi si n ṣe lọwọ fihan pe o ṣeeṣe ki ẹranko naa ni nkan ṣe pẹlu ajakalẹ arun Covid-19.

Ẹkunrẹrẹ fidio ohun re e;