Sunday Igboho: 'Ǹkan tÍ Sunday Igboho Ṣe ní Ibarapa tún ti ṣelẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun'

Sunday Igboho: 'Ǹkan tÍ Sunday Igboho Ṣe ní Ibarapa tún ti ṣelẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun'

Adari egbe Miyetti Allah ni ile Yoruba, Muhammed Kabir Labar nkan tÍ Sunday Igboho Ṣe ní Ibarapa tún ti ṣelẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun

Kabir Labar lo so bee fun BBC Yoruba.

Labar ni Sunday Igboho dana sun ile Seriki ni agbegbe Ijọba ibilẹ Igbowa, ni ipinlẹ Ogun.