Ipele to nira:
Tẹ́ ibi lati ka itọni
 • Fi ọrọ Geesi we eda ọrọ rẹ ni Yoruba
 • Lati safiwe, tẹ odo to wa lẹba ọrọ Geesi, ki o si tun tẹ odo to sunmọ eda rẹ ni ede Yoruba
 • Tẹ bọtini to wa labẹ idanwo yi lati wo iye to gba
 • Sun siwaju lati ipele ikarun si omiran
 • Ipele marun lo wa.Ri daju wipe o pari gbogbo wọn!

Bawo lo se gbọ Yoruba si?

Oni ni ayajọ ede abinibi lagbaye, akori fun ọdun 2019 ni '''Ede abinibi se pataki fun idagbasoke, alaafia ati ipẹtu saawọ''
 • O rorun (awọn eranko)

  • Bat - Adan
  • Camel - Rakunmi
  • Cow - Maalu
  • Ostrich - Ogongo
  • Lizard - Alangba
  • Swan - Pẹpẹyẹ odo
  • Tiger - Ẹkun
 • Ko nira

  • Five Hundred - Ẹẹdẹgbẹta
  • Fifty - Aadọta
  • Seven Million - Miliọnu meje
  • Five Thousand - Ẹgbẹrun marun
  • Twenty Five - Marundinlọgbọn
  • Thirty Five - Marundinlogoji
  • Seventy Five - Marundinlọgọrin
 • O nira (omi)

  • Ocean - Okun
  • Lake - Adagun odo
  • River - Odo
  • Pond - Adagun odo kekere
  • Stream - Odo to n san
  • Dam - Adagun odo omi ẹrọ
  • Spring - Odo kekere to n san
footer img