Ẹsin igbagbọ

 1. Video content

  Video caption: Kayode Abiara: Ọmọ Nàíjíríà, ẹ má ba ọkàn jẹ́ lórí ààbò tó mẹ́hẹ, ewu ìgbà ìkẹyìn ló jẹ́

  Wolii Kayode Abiara tún ṣàlàyé pé, ọbẹ̀ tó dùn owó ló paá lọ̀rọ̀ iléèwé àwọn ẹlẹ́sìn jẹ́, kò sì yẹ káwọn èèyàn tàbùkù rẹ̀.

 2. Video content

  Video caption: Imam Abubakar: ìdí tí mi ò fi fi méní pe méjì láti ṣí Mọ́sálásí fáwọn Krìstẹ́nì

  Mo sọkún bíi ọmọ́dé nígbà tí à ń gbé òkú àwọn tí wọ́n ti pa, Imam Abubakar sọ fún BBC.

 3. Video content

  Video caption: Wòlíì Kasali sọrọ nípa awuyewuye pé o lè ìyàwó rẹ̀ jáde nílé

  Wòlíì Kasali ní Dolapo Awosika kò lò lè ọlọmọ máàrún kúrò nílé òun

 4. Video content

  Video caption: Àlùfáà Joel Olugbenga: Bíbélì kò ní kéèyàn dúró títí ọkọ rẹ̀ yóò fi lù ú pa

  Níbi Ìpàdé ìtagbangba BBC Yorùbá lórí ìwà ipá nínú ilé, Àlùfáà Joel Olugbenga ṣàlàyé ohun tó yẹ kí lọ́kọláya ó mọ̀ fún ìgbeyawó alárinrin.