Ila-oorun ilẹ Afrika

 1. School

  Ògbóntarìgì olùkọ́ni ọmọ ilẹ̀ Kenya Peter Tabichi gba àwọn òbí nímọ̀ràn bí wọ́n ṣe leè kọ́ àwọn ọmọ wọn nílé lásìkò ìgbélé Coronavirus.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Idanwo abẹrẹ covid-19 nilẹ Gẹeṣi

  Ẹ gbẹ onimọ ijinlẹ oogun oyinbo kan wa ni fasiti Oxford nibi ti wọn ti n ṣagbeyẹwo abẹrẹ kan ti wọn n pe ni ''ChAdOx1 nCoV-19.''

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: East Africa: Àwọn kokoro ti ba èrè oko jẹ nílẹ̀ Afirika

  Àwọn agbẹ ni orilẹẹde Ethiopia ati Kenya to fi de Yeyem lo fi igbe ta, lẹyin ti kokoro esu ba gbogbo ere oko wọn jẹ.

 4. Daniel arap Moi

  Arap Moi, olóṣèlú tó ṣe ìjọba orílẹ́èdè kenya fún ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n, ti àwọn èèyàn ń rántí ìjọba rẹ̀ fún ìwà àjẹbánu àti ọrọ̀ ajé tó dẹnu kọlẹ̀ ti kú.

  Kà Síwájú Síi
  next