Robert Mugabe

  1. Video content

    Video caption: Robert Mugabe: Ọmọ Káfíńtà, olùkọ́ àti akọni òṣèlú níí ṣe

    Ààrẹ Mugabe di alátakò àwọn ìlú òkèèrè pàápà jùlọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sí, tí Zimbabwe gba òmìnira lọ́wọ́ wọn, Mugabe sì pe Gẹ̀ẹ́sí ní ''ọ̀tá orílẹ́èdè rẹ̀''