Aisan ọkan

 1. Video content

  Video caption: Igangan Mayhem: Obìnrin Fulani kan ní òun pàdánù ọkọ, ọmọ mẹ́ta àti gbogbo dúkìá torí ìjà

  Aishatu Saado ba BBC Yoruba sọrọ lati salaye ipo ibanujẹ to wa nitori laasigbo to waye laarin ẹya Fulani ati Yoruba nilu Igangan.

 2. igbeyawo

  Dokita Ibrahim Musa to jẹ akọṣẹ-mọṣẹ nipa arun inu ẹjẹ sọ pe, igbeyawo laarin ibatan ni ewu ninu nitori awọ̀n arun ajẹ́bi ti wọn le jogun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Hepatitis: A kò leè kóo nípa dídìmọ́ ara ẹni

  BBC Yorùbá ṣàlàyé kíkún nínú Làá hàn mí nípa àrùn jẹ̀dọ̀-jẹ̀dọ̀, bí a sẹ lè kóo àti àwọn oriṣii rẹ̀ tó wà.

 4. Video content

  Video caption: Urine Colour: Fídíò Lahanmi yìí ló ń ṣàlàyé nípa ọ̀pọ̀ àìsàǹ tó rọ̀ mọ́ bí ìtọ̀ wa ṣe rí

  BBC Yoruba se akojọpọ awọn aisan to lee fi oju han wa nipa bi itọ wa ba se ri lati se ilanilọyẹ nipa ilera wa.

 5. Ìpínlẹ̀ Eko pèsè ètò ìlera ọ̀fẹ́ fún àwọn aláboyún

  Gomina ipinle Eko. Babajide Sanwo-Olu ti pase eto iwosan ofe fun awon alaisan ati awọn alaboyun to ba ti lo si ile iwosan ijoba ni ipinle naa.

  Gomina Babajide Sanwo-olu fi lede bẹẹ loju ẹrọ ikansiraẹni Twitter wọn.

  Gomina Sanwo Olu ni awọ̀n yoo san owo iwosan awọn ti wọ̀n ba ṣiṣẹ abẹ fun ati awọn ti wọn ba n gba itọju pajawiri lọwọ.

  gomina babajide sanwoolu

  Bakan naa ni gomina naa ni awon alaboyun to ba fe bimo, yala iṣẹ abẹ ko gbẹyin ninu eto yii.

  Gomina naa ni eyi yio tun mu irorun ba awon eniyan lasiko igbele lati kapa itankalẹ arun Coronavirus.

  View more on twitter