Ede

 1. Video content

  Video caption: Yoruba Culture: Wo àwọn ẹ̀yà ara rẹ̀ níbí lédè Yorùba

  Melo èdè abínibí rẹ lo mọ̀ dáadáa?

 2. Video content

  Video caption: Àṣà àti ìgbàgbọ́ Yorùbá ni pé òbí wọn máa ń padà wá sáyé

  BBC Yorùbá jáde lọ bèèrè ìdí ti a fi ń sọ ọmọ ni Yetunde ki àwọn èwe ìwòyí lè kọ́ ẹ̀kọ́ síi nípa àṣà àti ìgbàgbọ́ Yorùbá.

 3. Video content

  Video caption: Òwe: Kí ni ìtumọ̀ òwe ikú tó ń pa ojúgbà ẹni?

  BBC Yoruba fẹ mọ bi awọn ọmọ Kaarọ Oojire se gbọ Yoruba si la se ni kẹ pari owe ‘Iku to n pa ojugba ẹni...’

 4. Video content

  Video caption: Ti o bá dá ara ẹ lójú, ki ẹni tó n ṣe irun kí n gbọ́?

  Ìgbágà Àṣà àti ìṣe Yorùbá ló jẹ́ BBC Yorùbá lógún pé ki ó má parun, èyí ló mú wa jáde lọ bèèrè ìkíni fáwọn onídìrí.

 5. Video content

  Video caption: Yoruba Language: Ṣé ẹ mọ ìdí tí ọmọ fi ń jẹ́ orúkọ yìí?

  Bí àwọn èèyàn ṣe ń fèsì ni wọ́n ti ń fi ojú na ara wọn ní máàkì bóyá mo yege tàbí n kò yege.

 6. Video content

  Video caption: Yorùbá dùn lédè, sáré pé gbólóhùn yìí wò tóo bá dá ara rẹ lójú

  Ọ̀bọ ń gbọ́bọ g'ọ̀pẹ jẹ ọkan lára àwọn gbólóhùn ọ̀rọ̀ akọ́nilẹ́nu tí Yorùbá fi ń kọ́ ọmọdé ni ọ̀rọ̀ sísọ àti ìdánilárayá.

 7. Video content

  Video caption: Àṣà àti èdè Yorùbá dùn púpọ̀, o ní ìtumọ̀ kíkún

  Ọkan lára ìdí tí a fi dá BBC Yorùbá sílẹ̀ ni kí àṣà Yorùbá má parùn, èyí ni a ṣe jáde lọ bèèrè irúfẹ́ ọmọ tí Yorùbá ń pè ni Olugbodi.

 8. Video content

  Video caption: Àmì ohùn ṣe pàtàkì nínú èdè Yorùbá púpọ̀

  BBC Yorùbá jáde lọ bèèrè àmì ohùn tó wà lórí ọ̀rọ̀: Igba ko lọ bi orere ni èyí tí ògidì àwọn ọmọ Yorùbá ti dán ara wò.