Iwadi Isegun

 1. Ọmọ ti wọn pa

  Ayẹwo fihan pe ọta ibọn bá Jumoke ni aya eyi to ṣakoba fun ẹdẹforo rẹ amọ ileesẹ ọlọpaa ni o ṣeéṣe ko jẹ pe awọn kan lo gun ùn lọbẹ pa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Pregnant dead mummy: Ṣé ẹ ti gbọ́ nípa òkú gbígbẹ́ tí wọ́n ṣì bá oyún nínú rẹ̀?

  Awọn onimọ Sayẹnsi lagbaye ṣẹṣẹ tun ṣawari oku ọlọjọ pipẹ kan pẹlu oyun ninu ni

 3. Video content

  Video caption: Snail Slim Soap: Wo ọ̀pọ̀ àǹfààní tó wà nínú lílo ọ̀ṣẹ tí wọn fi omi ìgbín ṣe láti fọ ojú?

  Iwadii kan ree to sọ nipa ọpọ anfaani to wa nidi lilo omi ara igbin to n yọ, fi se ọsẹ lati fi fọ oju rẹ.

 4. President Buhari Trip to London: Ǹkan márùn-ún tó ṣẹ̀lẹ̀ nígbà tí ààrẹ Muhammadu Buhari rín ìrìnàjò lọ London

  Ọ̀pọ̀ ọmọ Nàìjíríà ló n fàpa jánú pé láti ìgbà tí ààrẹ Muhammadu Buhari ti gori oye, lo ti n rin ìrìn àjò lọ sí ilẹ̀ òkèrè láti lọ gba ìtọ́jú.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Covid-19: Wo ìròyìn òfegè mẹ́jọ táwọn adarí ẹ̀sìn ń sọ nípa àbẹ́rẹ́ àjẹsára Coronavirus

  Oluwadi nipa abẹrẹ ajẹsara to n tako arun Coronavirus ni fasiti Washinton, Kolina Koltai salaye fun BBC nipa ìroyin ofege to lu igboro pa.

 6. Video content

  Video caption: Big breast: Oluwatosin Adegboro, Oluwaseun Amoo, Remi Fatolu: Ẹlòmíì ń fi irú ọyàn wa tọrọ

  Lẹ́yìn ifọrọwanilẹnuwo BBC pẹlu Remi Fatolu, ọpọ obinrin miran to lọyan naa tún ti jáde sita sọrọ soke nipa idẹyẹsi ti oju wọn n ri.