Ere Bọọlu

 1. Video content

  Video caption: Squash: Dele Oladejo ní iṣẹ́ ńlá ni eré ìdárayá Squash, olówó àti akọni ẹ̀dá ló ń gbá a

  Dokita Oludele Oladejo lo se agbatẹru idije ere idaraya Squash laipẹ yii fun awọn ọjẹ wẹwẹ akẹkọọ to nifẹ si ere idaraya yii.

 2. Football

  Awọn ẹgbẹ agbabọọlu mẹfa to n kopa ninu idije Premier League ti yọ ara wọn kuro ninu idije European Super League ti wọn ṣẹṣẹ gbe kalẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next