Ipinlẹ Jigawa

 1. Video content

  Video caption: Life saver car: Ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ yì ti gba ẹ̀mí ọ̀pọ̀ aláboyún àtọmọ ọwọ́ lá ní Jigawa

  Ilé ìwòsàn jínnà pupọ sí abule Bardo, ni awọn obinrin wọn ba gbe igbesẹ akin.

 2. Video content

  Video caption: Ọ̀sìn ewúrẹ́ tí mò n ṣe le mú mi figa-gbága pẹ̀lú àwọn tó n gba owó oṣù

  Obinrin yii to jẹ oniṣowo ewurẹ sọ pe owo ti oun n ri lara iṣẹ naa ju ti oniṣẹ oṣu lọ.

 3. Awọn ọlọkada lati Jigawa

  Agbẹjọro fun awọn ọlọkada naa ni ijọba Eko gbọdọ san owo gba ma binu fun wọn, nitori wọn ti wọn mọle lọna aitọ, lai se pe wọn jẹ ọdaran.

  Kà Síwájú Síi
  next