Awujọ

 1. Video content

  Video caption: LASTMA Yesufa: Àwọn dókítà gbìyànjú lórí ojú mi ṣùgbọ́n...

  Ọ̀rọ̀ ìfẹ́... wo afọ́jú LASTMA tó ṣe ìgbéyàwó alárinrin lẹ́yìn ti ojú rẹ̀ fọ́ lẹ́nu iṣẹ́ ẹṣọ̀ ààbò ojú pópó

 2. Video content

  Video caption: Sunday Igboho fulani ultimatum: Àwọn ará Kebbi àti Zamfara ló n jínígbé ní Oke Ogun- Serik

  Ti ijọba kò ba did fun aabo ara ilu, bo pẹ, bo ya, ara ilu a dide funra rẹ ni ọrọ Sunday Igboho

 3. Video content

  Video caption: America Inauguration Joe: Wo àwọn eré orí ìtàgé tí Donald Trump ṣe kó tó fi ipò aàrẹ sílẹ̀

  Lọ́là ni Donald Trump jáde ti Joe Biden yoo bẹ̀rẹ̀ si ni tukọ aleefa ijọba orilẹ-ede America

 4. Video content

  Video caption: BIAFRA at 50: Ìhàlẹ̀ ológun ni Gowon ni ká kọ́kọ́ fi bẹ̀rẹ̀- Aladejẹbi

  Ọkan pàtàkì lára àwọn ṣọ́jà tó ja ogun BIAFRA, Gabriel Aladejẹbi tó jẹ́ ẹni ọdún méjìlélọ́gọ́rin sọ̀rọ̀ lórí ohun ti ojú ri nígbà náà.