Igbesi Aye

 1. Video content

  Video caption: Ìsẹ̀lẹ̀ jákèjádò orílẹ̀èdè àgbáyé láàárín ìṣẹ́jú kan

  Àkójọpọ̀ ìsẹ̀lẹ̀ jákèjádò àgbáyé láàárín ìṣẹ́jú kan lórí BBC.

 2. Iyawo to n di mọ ọkọ rẹ

  Ẹni tó ṣe agbátẹru ayẹyẹ Bristol ọ̀hún ṣàlàyé pé, etò ilé tuntun tieọn fẹ́ kọ náà yóò ṣe àkóbá fún àwọn igi tó mẹ́rìnléládọ́rin.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Bobrisky

  Okuneye Idris Olarenwaju di ọkan gboogi lara awọn ilumọọka laarin awọn ọdọ ni Naijiria lẹyin to pa orukọ da si Bobrisky to si bẹrẹ si n mura bii obinrin.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Video content

  Video caption: Ado Ekiti Blind Couple: Tọkọ-taya Oke ní Ọ́ba òkè ló fi àwọn dá àrà tó wù ú

  Tọkọ-taya Oke wa n rọ awọn eeyan awujọ lati ye ro pe ko yẹ ki iru awọn eeyan to ba ni ipenija bayii jade laye tabi pe o ti tan fun wọn.

 5. Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi kẹta

  BBC Yoruba se akojọpọ ipa manigbagbe ti Alaafin tilu Oyo, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi ko lori itẹ lati aadọta ọdun sẹyin.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Ọdun to kọja ni wọn ri okuta iranti lorukọ Agboola Brownie ni Warsaw

  BBC Yoruba se akojọpọ isẹ takuntakun ti ọmọ Kaarọ Oojire kan, August Agboola Brownie ṣe nilẹ Poland lasiko ogun agbaye keji, eyi to sọ di akọni manigbagbe.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Video content

  Video caption: 2020 in Retrospect: Ìjàmbá iná, ilé tó dàwó, ìwọ́de àti àrùn Covid-19 wà lára ìṣẹ̀lẹ̀ 2020

  BBC Yoruba se akojọpọ awọn isẹlẹ manigbagbe to waye ninu ọdun 2020.