Etọ awọn obinrin

 1. Video content

  Video caption: Kìí ṣe ọmọbìnrin nìkan ni Ọlọ́run pàṣẹ fún láti pa ìbálé mọ́

  Arabinrin Okeowo, to da ajọ TGCON silẹ lati ma polongo pipa ibale mọ ba BBC Yoruba sọrọ lori pataki rẹ.

 2. Zarka in the hospital

  Owu jijẹ lo mu ki ọkọ Zarka gé imu rẹ. Ọpẹlọpẹ iṣẹ abẹti wọn ṣe fun un lo ṣe iranwọ lati mu oju rẹ pada bọ sipo amọ ẹru ṣi n ba Zarka tori ọmọ to da wọn pọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Sexual Compatibility: Ìye ìgbà tóo ní ìbálòpọ̀ kọ́ ló ń jẹ́ kí abẹ́ obìnrin fẹ̀

  Ẹ gbọ́ bí ìgbádùn ìbálòpọ̀ ṣe máa ń rí lẹ́nu ọmọ Yorùbá onímọ̀ nípa ìbálòpọ̀ lákọ lábo, Yinka TNT.

 4. Video content

  Video caption: Ó dára kí obìnrin níṣẹ́ lọ́wọ́ - Toyin Lawani

  Kò sí okùnrin tó fẹ́ gbé "Liability" sílé láyé òde òní- Ronke Ojo