Ajo eleto ilere lagbaye

 1. Aarẹ Muhammadu Buhari

  Minisita abẹle fun eto ilera ni Naijiria, Dokita Olorunnimbe Mamora lo sọrọ yii nibi ayẹyẹ ayajọ oogun ibilẹ to waye niluu Abuja.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Suicide Prevention: ìwọ́de yìí wáyé láti gbógun ti pípa ara ẹni

  Òní ni àyàjọ́ ìgbógunti pípa ara ẹni láwùjọ ní èyí tí àjọ Glittoh pàrọwà ìforítì àti ìfẹ́ ní ọ̀nà àbáyọ.

 3. Awọn ọmọ ologun

  Femi Falana ni abọ iwadii ileesẹ ologun ti Buhari se ti fihan pe awọn aadọrin sọja naa ko jẹbi ibeere wọn fun ipese ohun ijagun to poju owo lati doju kọ Boko Haram.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. abẹ́rẹ́ àjẹsára COVID-19

  Araalu kan tiẹ ni iroyin ti awọn n gbọ ni pe awọn eeyan to gba abẹrẹ naa n ṣaisan, bo tilẹ jẹ pe ko si ayẹwo to fi idi ọrọ yii mulẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Oyin

  Awọn onimọ Sayẹnsi ni Australia ti fi iwadii wọn sita pe oro inu agbọn oloyin maa n pa kokoro aisan jẹjẹrẹ to buru ninu ọmu.

  Kà Síwájú Síi
  next