Orilẹede Benin

 1. Sunday Igboho

  Laipẹ yii ni fọnran kan jade sori ayelujara, nibi ti Igboho ti n fi ẹsun aikoju osunwọn kan awọn agbẹjọro naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Yoruba Nation Agitation: Tani ó ó da ẹgbẹ́ àwọn ajìjàgbara Yorùbá Nation rú

  Adarí ẹgbẹ́ Yorùbá Kọya Deji Osibogun ṣàlàyé fún BBC Yorùbá pé, lóòtọ́ ni ìpádé wáye láti kórajọ́ pọ̀ fún ìlọ̀síwájú gbogbo Yorùbá lápapọ̀.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Sunday Igboho: Femi Falani ní ẹjọ́ Igboho ní Cotonou ń kọ́ àwọn amòfin Nàíjíríà ní ẹ̀kọ́

  Femi Falana ba BBC Yoruba sọrọ lori awọn ilana arufin ti ijọba Naijiria n gbe lori ọrọ Sunday Igboho ati Nnamdi Kanu.

 4. Sunday Igboho ati Banji Akitoye

  Àtẹ̀jáde ti Ilana Omo Oodua fisita lọ́jọ́ Aiku ló ṣàlàyé pé Banji Akitoye wà ni òrílẹ̀-èdè Cotonou láti mójútó igbẹ́jọ́ Sunday Igboho.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Aworan Igboho

  Malik Olusegun Falola sọ fun awọn akọroyin pe ijọba Benin mọọmọ fi Igboho si ahamọ ni, ki awuyewuye to n waye lori ọrọ rẹ le dinku.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Sunday Igboho nibi iwọde

  Ile ẹjọ lo paṣẹ nibi igbẹjọ Sunday Igboho lọjọ Aje pe ki wọn mu Igboho kuro ni atimọle ọlọpaa.

  Kà Síwájú Síi
  next