Rogbodiyan arun Ebọla

 1. Dokita Ameyo Stellah Adadevoh

  Awọn akinkanju ko wọn ni idile oloogbe Stellah Adadevoh nitori lara awọn babanla rẹ ni Ọmọwe Herber Macaulay wa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Ebola Outbreak

  Ilé asòfin àpapọ̀ ti sekìlọ̀ pé ó seése kí Naijiria lùgbàdì àìsàn Ebola tí wọ́n kò bá tètè mú ètò ìlerà lọkunkundun.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Ebola Virus: ìdí tí Ebola fi ń tàn kálẹ̀

  Ebola tún ti dé DR Congo àti Uganda ní èyí tí wọ́n ní kò ṣẹ̀yìn ẹran ìgbẹ́ Àdán, Ọ̀bọ, ìnàkí àti Ìgalà.