Egbẹ Oselu Alaburada (PDP)

 1. Olagunsoye Oyinlola ati Taofeek Oladejo Arapaja

  Seyi Makinde ni ẹgbẹ oṣelu PDP yoo gbajọba lọdun 2023, eti yoo si tun Naijiria ṣe yatọ si bi nnkan ṣe dẹnu kọlẹ lasiko ijọba ẹgbe APC to wa lode.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Seyi Makinde: Kò sí ìjà láàrin èmi àti Fayose, àjọṣepọ̀ wa gún régé

  Gomina Seyi Makinde, ninu ifọrọwerọ rẹ pẹku BBC Yoruba, tun sọ nipa aayan rẹ lori eto ẹkọ, atunse oju popo yika ipinlẹ Oyo ati ipese eto ilera to yanranti fawọn eeyan ipinlẹ Oyo.

 3. Video content

  Video caption: PDP Convention: Àrà ọ̀tọ̀ ní ìdìbò 'convention' tọ̀tẹ̀ yí, òru mọ́jú la ti yanjú
 4. Uche Secondus

  Ọdun 2017 ni Secondus gori alefa gẹgẹ bii alaga ẹgbẹ oṣelu PDP lẹyin to ti kọkọ wa lori oye naa gẹgẹ bii alaga fidihẹ lati ọdun 2015 si 2016.

  Kà Síwájú Síi
  next