Ẹ̀kún omi

 1. Video content

  Video caption: Oshogbo Heavy Rainfall: Ọ̀pọ̀ ẹ̀mí àti dúkìá àìmoye mílíọ̀nú naira ṣòfò nínú ìjàmbá omíya

  Ọpọ dukia lo ba iṣẹlẹ naa lọ eyi ti a gbọ pe o bẹrẹ si ni rọ lati oru ọjọ Iṣẹgun ti ko si da titi di owurọ kutu Ọjọru.

 2. Flood: O kéré tán ènìyàn 80 ló ti d'òkú nítori òjò àrọ̀rọdá tó fa omí yalé agbara ya sọọbù

  Ìròyìn sọ pé ní orílẹ̀-èdè Germany, West Germany ni ọ̀rọ̀ náà kàn jùlọ, eyí tí àwọn odò ya wọ ìfgborò tí ọ̀pọ̀ ilé sì rì sí abẹ́ omi.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Ketu Flood: Ọ̀tọ̀ lọ̀rọ̀ táa ń pè ìjọba sí o, ẹ wá wò ó

  Awọn olugbe Ketu nibi ti iroyin ni agbara ojo wọ ọmọ meji lọ ni ọtọ lohun tawọn n pe akiyesi ijọba si.

 4. Video content

  Video caption: Flood: Ọ̀pọ́ Dúkìá ló sọnù ní 2019 lásìkò tí ìjọba ṣí ’dáàmù Ọyan’

  Àjọ Ogun-Oshun River Basin Development Authority ti ni awọn yóò ṣi daamu Oyan laipẹ.

 5. Irun jimọ ni ilu Ilọrin

  Laipẹ ni ijọba Kwara ati awọn igbimọ Ulama ṣe Ipade lati faaye gba irun Jimọ lawọn mọsalasi lẹyin bi oṣu mẹta ti isede Covid-19.

  Kà Síwájú Síi
  next