Ipinlẹ Ondo

 1. Video content

  Video caption: Idanre Hills, Ondo: Ogun gan kò láyà láti dédé gun òkè Idanre

  O ju igba ọdun ti awọn ara ilu Idanre fi gbe ori oke gogoro naa ki wọn to ko lọ si isalẹ.

 2. Video content

  Video caption: Òkè Ìdànrè: Òkè tó kéré jùlọ jẹ́ ẹsẹ̀ bàtà ẹgbẹ̀rún mẹ́ta

  Ori oke idanre ni awọn eeyan ilu naa n gbe laye atijọ, nibiti ile-ẹkọ, aafin ọba ati oniruuru ile alarabara wa.

 3. Video content

  Video caption: Akure Kidnap: Àwọn abiyamọ fẹ̀hónúhàn lórí ọmọ tí wan jígbé nílé ìjọsìn Akurẹ

  Ẹgbẹ́ obìnrin (NCWS) ẹ̀ká ìpínlẹ̀ Ondo fárigá lórí ohun tó n ṣẹlẹ̀ nípa Gold tí wọ́n jí gbé, wọ́n bẹ Akeredolu kó bá wọn dá síi.

 4. Aworan awon obinrin to n fehonu han lori Gold Kolawole

  Ilé ìjọsìn ni ìyá ọmọ náà ní òhun kò ti rí ọmọ òhun mọ́ láti àsìkò táwọn ti lọ ṣe ìjọsìn níbẹ̀ l'óṣù kan sẹ́yìn.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Video content

  Video caption: Ondo disability: Kò sí ẹni tí àkàndá kò lè ya ilé rẹ̀- Ayọdele

  Àwọn ajáfẹ́tọ̀ọ́ àkàndá ẹ̀dá ni ìpínlẹ̀ Ondo bá BBC sọ̀rọ̀ lórí ìpèníjà tó n kojú àkàndá àti ọ̀nà àbáyọ láwùjọ.

 6. Video content

  Video caption: Ondo Church Kidnap: Ẹ jọ̀ọ́ ẹ gbà wá o, kí wọ́n má fọwọ́ ọlá gbá wa lójú

  Bàbá, ìyà àti ìyá ìyà ọmọ ní bíi bàrà ní àwọn ọlọ́pàá pásítọ̀ lu àwọn tórí ọmọ ọdún kan tí wọ́n ń wá.

 7. Eniola Gold ati awọn obi rẹ

  Titi di igba ti a n ko iroyin yii jọ, igbiyanju lati ba olori ijọ ti ọmọ naa ti sọnu, ijọ Sọ titobi rẹ, sọrọ lo ja si pabo, ti ko si gbe ẹrọ ibanisọrọ rẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next