Ilera ọpọlọ

 1. Video content

  Video caption: N kò lè ṣe gẹ́gẹ́ bí ọkùnrin, ṣùgbọ́n n kò mọ̀ títí tí mo fi ṣe ìgbéyàwó
 2. Awọn ọmọ ologun

  Femi Falana ni abọ iwadii ileesẹ ologun ti Buhari se ti fihan pe awọn aadọrin sọja naa ko jẹbi ibeere wọn fun ipese ohun ijagun to poju owo lati doju kọ Boko Haram.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Video content

  Video caption: Thyroid foundation: eéwo ni mo kọ́ka pè é àṣé gẹ̀gẹ̀ ọrùn tó lé ẹbí, ará àti ọ̀rẹ́ ni mo n

  Adebukola Adediran royin ohun ti oju rẹ ri ko to bọ lọwọ arun gẹgẹ ọrun, o rọ awọn eniyan lati kiyesi ọrun wọn.

 4. Video content

  Video caption: Man gunned in the mouth: Peter Omotoye ní ìbọn nínú ẹnu yìí yí ìgbé ayé òun padà pátápátá

  Ọmọ Alagba Peter ni gbogbo ounjẹ lawọn n fi ẹrọ lọ ko di olomi ki o to lee fi paipu rọba ti wọn gbe si i nimu jẹun tabi lo oogun.

 5. Video content

  Video caption: Babatunde Ayanniyi One hand driver: Èrò pé kí mo fẹ́ dà láyé mọ́ báyií bí wọ́n ṣe gé ọwọ́

  Bi Ayanniyi ṣe n ṣe e to fi ọwọ kan to ku wa ọkọ ko yeni to boya ninu irọrun ni tabi ninu irora. Ko si ẹni ti yoo ri i ti ko ni ya lẹnu.