Iyipada Akọ-sabo ati Abo-sakọ

 1. Idris Olarewaju

  Bobrisky fi kún pé bi oun yóò ba tilẹ̀ gba ẹ̀bẹ̀ rẹ̀ yóò sùn mọjú ní àgọ́ ọlọàá yóò ra fóònù túntun Iphone X Max bákan náà ni yóò tún móto oun ṣe .

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Aworan ọmọ ti wọn ipa ba lopọ

  Ọmọ ọdun meje ni oniroyin Elizabeth Ohene wa nigba ti iṣẹlẹ naa ṣelẹ, ṣugbọn ko sọ fun ẹnikan nigba nigba naa.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Bobrisky

  Jiti Ogunye ṣalaye pe, ofin ilẹ wa ko faye gba èèyàn ‘koṣakọ-koṣabo’, nitorinaa, kíkọ́ ìbùdó ọ̀tọ̀ fún wọn, ko le fẹsẹ mu lẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. Awọn eeyan lahamọ ni Kaduna

  Ileeṣẹ ọlọpaa fidi rẹ mulẹ pe awọn eeyan naa ti gbogbo wọn jẹ ọkunrin wa lati orilẹede Burkina Faso, Mali atawọn orilẹede ile Afirika miiran.

  Kà Síwájú Síi
  next