Eto Ifowopamọ

 1. CBN

  Banki apapọ lorilẹede Naijiria, CBN ti fi lede ọna ti awọn eniyan le gba lati ri owo ayalọ fun awọn eniyan ti ajakalẹ Boko Haram ṣe ipalara fun ọrọ aje.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. USSD

  Báǹkì àpapọ̀ Nàìjíríà ni òfin tuntun náà wà lati yanju aáwọ̀ tó má n wáye láàrín àwọn ilé iṣẹ́ tó n ri sí ibáraẹnisọ̀rọ̀ àti àwọn báǹkì.

  Kà Síwájú Síi
  next
 3. Kaadi NIN

  Ọpọ eeyan lo n tiraka lati gba aapu lori ayelujara fun iforukọsilẹ NIN wọn eyi to le se akoba fun wọn, ti wọn ba gba ayederu aapu.

  Kà Síwájú Síi
  next
 4. FCMB Marriage Scandal: À ń ṣe ìwádìá lọ́wọ́ lórí ọ̀rọ̀ ọgá agbà iṣẹ́ wa-FCMB

  Atẹjade kan ti FCMB fisita lori isẹlẹ to n mi oju opo ayelujara titi naa ní ìgbìmọ̀ alakoso ilé ìfówópamọ́ ọhun yoo gbe abọ iwadii rẹ sita laipẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 5. Apẹrẹ fọọmu iforukọsilẹ naa ati kaadi idanimọ ọhun

  BBC Yoruba se akojọpọ awọn ọna to le gba lati ri nọmba idanimọ NIN gba, ti ijọba Naijiria sọ di dandan fún gbogbo èèyàn tó bá ń lo fóònù.

  Kà Síwájú Síi
  next
 6. Awọn onibara banki

  Gbogbo ẹbẹ ti banki CBN se lati mu ki ile ẹjọ wọgile igbẹjọ naa lo ja si pabo, ti adajọ si tun koro oju si ọwọ tawọn ileesẹ ijọba fi maa n mu idajọ ileẹjọ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 7. Ile ifowopamọ Union Bank

  Ileeṣẹ ọlọpaa ni agọ ọlọpaa to wa ni Ode-Irele lawọn ọdaran naa kọkọ kọlu ki wọn to morile ile ifowopamọ Union Bank.

  Kà Síwájú Síi
  next