Àwọn èèyàn tó ńjà fún òmìnira orílẹ̀èdè Biafra

 1. Ayo Adebanjo and Buhari

  Akọwe agba ẹgbẹ Afenifere, Sola Ebiseni lo sọ ọrọ naa ninu atẹjade kan pe ijọba Buhari ti ja awọn ọmọ Naijiria kulẹ, o si tọ ki awọn araalu maa sọrọ abuku si i.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: BIAFRA at 50: Ìhàlẹ̀ ológun ni Gowon ni ká kọ́kọ́ fi bẹ̀rẹ̀- Aladejẹbi

  Ọkan pàtàkì lára àwọn ṣọ́jà tó ja ogun BIAFRA, Gabriel Aladejẹbi tó jẹ́ ẹni ọdún méjìlélọ́gọ́rin sọ̀rọ̀ lórí ohun ti ojú ri nígbà náà.