Ere Idaraya

 1. Aworan Dudu Heritage, isinku rẹ ati Bimbọ Oshin

  Wọn bẹrẹ eto ọhun pẹlu gbingbin igi kan ni gbagede ti wọn ti n gba gọọfu naa lati ṣe iranti rẹ, ati lati ṣe apẹrẹ pe bo tilẹ jẹ pe o ti jade laye, yoo si wa laaye sibẹ.

  Kà Síwájú Síi
  next
 2. Video content

  Video caption: Ridwan Oyekola: October 30 ni màá tún ìjà jà láti gba belt mi padà àmọ́ kò sí onígbọ̀wọ́

  Ridwan Oyekola tun ba BBC Yoruba sọrọ lori ẹdun ọkan rẹ bi ko se si onigbọwọ fun ija ẹsẹ kikan rẹ lati daabo bo bẹliti to gba , to si n bẹ ijọba lati dide si ẹbẹ rẹ.

 3. Video content

  Video caption: Latifat Tijani: Ìjọba Naijiria ń ṣèlérí láti mọ́ rírì mi àmọ́ láti 2016, pàbó ló ń já sí

  BBC Yoruba ba akanda elere idaraya, Latifat Tijani sọrọ lori ohun to n la kọja lẹyin to gba ami ẹyẹ fadaka fun Naijiria lọdun 2016 ati Wura lọdun 2020 láì ri iranwọ ijọba.

 4. Video content

  Video caption: Ridwan Scorpion Oyekola Boxer: Mo gba N10 Miliọ̀nù lórí ẹ̀ṣẹ́ jíjà àmọ́ ẹbí sọ mi di pòlòf

  Ridwan ni ẹbun owo miliọnu mẹwaa ti oun ri gba lọwọ Gomina ipinlẹ Oyo lo gbe oun jade gẹgẹ bi ilumọọka.

 5. Lionel Messi

  Agbaọjẹ agbabọọlu orilẹede Brazil to ti fẹyin ti naa sọ pe oun n gbọ oorun Champiọns League ni PSG bayii lẹyin ti Messi darapọ mọ wọn tan.

  Kà Síwájú Síi
  next